“Ti ibi, ti ire la wá ilé ayé” – Ọ̀rọ̀ àti Ìṣe Ìgboro ni Èkó: “We came into the world with good and bad” – Street Talk and Activities in Lagos

Èkó jẹ́ olú ìlú Nigeria fún ọpọlọpọ ọdún, ki wọn tó sọ Abuja di olú ìlú Nigeria, ṣùgbọ́n Èkó ṣi jẹ́ olú ìlú fún iṣẹ ọrọ̀ gbogbo Nigeria.  Nitori eyi, gbogbo ẹ̀yà Nigeria àti àwọn ará ìlú miran titi dé òkè-òkun/ìlú-òyinbó ló wà ni Èkó.

Yorùbá ni èdè ti wọn nsọ ni ìgboro Èkó, ṣùgbọ́n ọpọlọpọ gbọ èdè Gẹẹsi, pataki àwọn ti ki ṣé ọmọ Yorùbá.  Ẹ wo díẹ̀ ni àwọn ìṣe àti ọ̀rọ̀ ni ìgboro Èkó:

ENGLISH TRANSLATION

Lagos was the capital of Nigeria for many years before the capital was moved to Abuja, but Lagos remains the commercial capital of Nigeria.  As a result, every ethnic group in Nigeria and people from abroad/Europe are present in Lagos.

Share Button

Originally posted 2013-09-24 19:43:17. Republished by Blog Post Promoter

1 thought on ““Ti ibi, ti ire la wá ilé ayé” – Ọ̀rọ̀ àti Ìṣe Ìgboro ni Èkó: “We came into the world with good and bad” – Street Talk and Activities in Lagos

  1. gannzter

    Great slide show. One of the first things I learnt how to do in the Yoruba language back when I was about 10 was the swearing… The translation of Yoruba swear words and abusive language sound almost funny in this translation. To get a proper picture, one has to imagine a person screaming at the top of their lungs, veins bulging from their neck.

    Reply

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Time limit is exhausted. Please reload the CAPTCHA.