“Kí Kà ni Èdè Yorùbá” – “Counting or Numbers in Yoruba”

Yorùbá ni bi wọn ti ma a nka nkàn ki wọ́n tó bẹ̀rẹ̀ si ka a ni èdè Gẹ̀ẹ́sì.  Ẹ ṣe àyẹ̀wò kíkà ni èdè Yorùbá ni ojú ewé yi:

ENGLISH TRANSLATION

Counting or numbers in Yoruba before the introduction of counting in English.  Check out counting or numbers’ pronunciation on this page.

Share Button

Originally posted 2016-03-18 01:15:22. Republished by Blog Post Promoter

5 thoughts on ““Kí Kà ni Èdè Yorùbá” – “Counting or Numbers in Yoruba”

  1. Victor Williamson

    Ó náà dáà gidigidi gan ni. Ní èdè Yorùbá wọn máa ń kọ àwọn nọmba lílo ogún a ogún. Fún apẹ̀rẹ̀ 20 x 3 (ọgọ́ta), 20 x 4 (ọgọ́rin), 20 x 6 (ọgọ́fa), áti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

    Reply
  2. Oluwasegun Ojeyelu

    Good Morning

    Thank you for all your help to put up Yoruba language on internet for people like us. I will be glad if you can send me the link to Ẹ̀kọ́-Ìṣirò Ni Èdè Yorùbá – Simple Arithmetic In Yoruba Language as I really want to learn maths in Yoruba.

    Many Thanks
    Oluwasegun

    Reply
  3. Ayilara Rasaki Olawale

    Nje ona ti a le gba sise po wa nitori pe emi na ngbiyanju lati da iru eto yi sile. E le wo Mathsinyoruba.blogspot.com.

    Reply
    1. Bim A

      Dear Mr. Ayilara, I have tried to check out your blog and commend your efforts. Please explain further on how you think we can collaborate.

      Reply

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Time limit is exhausted. Please reload the CAPTCHA.