Àjọ̀dún Òmìnira Nigeria Kẹrindinlọgọta – Nigeria’s Fifty-six Independence Celebration

Àjọ̀dún Òmìnira Nigeria Kẹrindinlaadọta – Nigeria’s Fifty-six Independence Celebration. Courtesy: @theyorubablog

Àjọ̀dún Òmìnira Nigeria Kẹrindinlaadọta – Nigeria’s Fifty-six Independence Celebration. Courtesy: @theyorubablog

Share

2 thoughts on “Àjọ̀dún Òmìnira Nigeria Kẹrindinlọgọta – Nigeria’s Fifty-six Independence Celebration

 1. Ayoola Fadeyi

  Ẹ kú iṣẹ́ ọpọlọ. Kí Elédùmarè tún bọ̀ máa ṣe àbò lórí yín. Inú mi dùn láti ríi pé ẹ̀ ń ṣiṣẹ́ lórí bí èdè Yorùbá kò ṣe ní parun.

  Mo fẹ́ jẹ́ kí a jọ jíròrò lórí bi a ṣe lè sọwọ́ pọ̀ láti mú kí èdè Yorùbá fẹsẹ̀ múlẹ̀ lórí íńtánẹ̀tì.

  Reply
  1. Bim A Post author

   Inú mi dún lati dáhùn si ètò àti jọ jíròrò bi a ti lè mú èdè Yorùbá fẹsẹ̀ múlẹ̀ lóri ayélujára. Yorùbá ni “Nkan ẹni kò ni di púpọ̀, ki inú ẹni bàjẹ”, eyi lo fa ìdáhùn si ọ̀rọ̀ yi. Ẹ kàn si wà lóri àpò iwé ori ayélujára: theyorubablog@gmail.com, ki a ti ibẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ijíròrò.

   Reply

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Time limit is exhausted. Please reload the CAPTCHA.