A kú Ìdùnnú Ìdúpẹ́ – Happy Thanksgiving

Bi Ọlọrun ti ńdárí ẹ̀ṣẹ̀ ji èniyàn
Bi Olóri Òṣèlú Àmẹ́rikà ti ńdáríji tòlótòló
Bẹni ki èniyàn dári ji ẹni ti ó bá ṣẹ́, nitori ki a lè fi ìdùnnú dúpẹ́.

Olóri Òṣèlú Àmẹ́rikà dáríji tòlótòló – American President pardons the Turkey during Thanksgiving

 

 

Share

2 thoughts on “A kú Ìdùnnú Ìdúpẹ́ – Happy Thanksgiving

  1. Abimbola Adeosun

    dun Idupẹ, Mo nifẹ bulọọgi yii ati ni ireti pe gbogbo rẹ ni aṣeyọri pẹlu ohun gbogbo.

    Happy Thanksgiving!

    Reply

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Time limit is exhausted. Please reload the CAPTCHA.